Isa 32:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Warìri, ẹnyin obinrin ti o wà ni irọra; ki wahala ba nyin ẹnyin alafara: ẹ tú aṣọ, ki ẹ si wà ni ihòho, ki ẹ si dì àmure ẹgbẹ́ nyin.

Isa 32

Isa 32:7-17