Isa 3:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Niti awọn enia mi awọn ọmọde ni aninilara wọn, awọn obinrin si njọba wọn. A! enia mi, awọn ti nyẹ ọ si mu ọ ṣìna, nwọn si npa ipa-ọ̀na rẹ run.

Isa 3

Isa 3:3-21