Isa 29:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi alá iran oru li ọ̀pọlọpọ awọn orilẹ-ède ti mba Arieli jà yio ri; gbogbo ẹniti o bá ati on, ati odi agbara rẹ̀ jà, ti nwọn si pọ́n ọ loju.

Isa 29

Isa 29:1-17