Isa 23:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mu harpu kan, kiri ilu lọ, iwọ panṣaga obinrin ti a ti gbagbe; dá orin didùn: kọ orin pupọ̀ ki a le ranti rẹ.

Isa 23

Isa 23:9-18