Isa 22:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati li ọjọ na ni Oluwa, Oluwa awọn ọmọ-ogun yio pè lati sọkun, ati lati ṣọ̀fọ, ati lati fá ori, ati lati sán aṣọ ọ̀fọ.

Isa 22

Isa 22:5-21