Isa 21:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori bayi li Oluwa ti sọ fun mi, ki ọdun kan to pe, gẹgẹ bi ọdun alagbaṣe, gbogbo ogo Kedari yio wọ̀.

Isa 21

Isa 21:14-17