Isa 21:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ ìpaka mi, ati ọkà ilẹ ìpaka mi: eyi ti emi ti gbọ́ lọdọ Oluwa awọn ọmọ-ọgun, Ọlọrun Israeli li emi ti sọ fun ọ.

Isa 21

Isa 21:3-12