Isa 21:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọ̀RỌ-ìmọ niti ijù okun. Gẹgẹ bi ãja gusù ti ikọja lọ; bẹ̃ni o ti ijù wá, lati ilẹ ti o li ẹ̀ru.

Isa 21

Isa 21:1-4