Isa 20:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa si wipe, Gẹgẹ bi Isaiah iranṣẹ mi ti rìn nihòho ati laibọ̀ bàta li ọdun mẹta fun ami ati iyanu lori Egipti ati lori Etiopia;

Isa 20

Isa 20:1-6