Isa 2:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ilẹ wọn kún fun oriṣa pẹlu; nwọn mbọ iṣẹ ọwọ́ ara wọn, eyiti ika awọn tikalawọn ti ṣe.

Isa 2

Isa 2:6-9