Isa 2:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lati lọ sinu pàlapala apata, ati soke apata sisán, nitori ibẹru Oluwa, ati nitori ogo ọlanla rẹ̀; nigbati o ba dide lati mì ilẹ aiye kijikiji.

Isa 2

Isa 2:16-22