Isa 2:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ọjọ Oluwa awọn ọmọ-ogun yio wà lori olukuluku ẹniti o rera, ti o si gberaga, ati lori olukuluku ẹniti a gbe soke, on li a o si rẹ̀ silẹ.

Isa 2

Isa 2:9-16