Isa 19:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li ọjọ na ni opopo kan yio wà lati Egipti de Assiria, awọn ara Assiria yio si wá si Egipti, awọn ara Egipti si Assiria, awọn ara Egipti yio si sìn pẹlu awọn ara Assiria.

Isa 19

Isa 19:14-25