Isa 19:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si gbe Egipti dide si Egipti: olukuluku yio si ba arakunrin rẹ̀ jà, ati olukuluku aladugbò rẹ̀; ilu yio dojukọ ilu, ati ijọba yio dojukọ ijọba.

Isa 19

Isa 19:1-5