Isa 19:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li ọjọ na ni ilu marun ni ilẹ Egipti yio fọ̀ ède Kenaani, ti nwọn o sì bura si Oluwa awọn ọmọ-ogun; a o ma pè ọkan ni Ilu ìparun.

Isa 19

Isa 19:16-23