Isa 19:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li ọjọ na ni Egipti yio dabi obinrin; yio si warìri, ẹ̀ru yio si bà a nitori mimì ọwọ́ Oluwa awọn ọmọ-ogun ti o mì le e lori.

Isa 19

Isa 19:12-20