Isa 18:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori bẹ̃li Oluwa sọ fun mi, emi o simi, emi o si gbèro ninu ibugbé mi, bi oru ọsángangan, ati bi awọsanma ìri, ninu oru ikorè.

Isa 18

Isa 18:3-5