Isa 17:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si dabi igbati olukorè nkó agbado jọ, ti o si nfi apá rẹ̀ rẹ́ ipẹ́-ọkà yio si dabi ẹniti nkó ipẹ́-ọkà jọ ni afonifoji Refaimu.

Isa 17

Isa 17:2-10