Isa 17:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Odi kì yio si si mọ ni Efraimu, ati ijọba ni Damasku, ati iyokù ti Siria: nwọn o dabi ogo awọn ọmọ Israeli, li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi.

Isa 17

Isa 17:1-10