Isa 16:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si ṣe, bi alarinkiri ẹiyẹ ti a le jade kuro ninu itẹ́-ẹiyẹ, bẹ̃ni ọmọbinrin Moabu yio ri ni iwọdò Arnoni.

Isa 16

Isa 16:1-6