Isa 15:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori awọn omi Nimrimu yio di ahoro: nitori koriko nrọgbẹ, eweko nkú lọ, ohun tutù kan kò si.

Isa 15

Isa 15:2-7