Isa 15:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

ỌRỌ-imọ̀ niti Moabu. Nitori li oru li a sọ Ari ti Moabu di ahoro, a si mu u dakẹ; nitori li oru li a sọ Kiri ti Moabu di ahoro, a si mu u dakẹ;

Isa 15

Isa 15:1-9