Isa 14:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si ṣe e ni ilẹ-ini fun õrẹ̀, ati àbata omi; emi o si fi ọwọ̀ iparun gbá a, li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi.

Isa 14

Isa 14:20-24