Isa 14:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ti o ri ọ yio tẹjumọ ọ, nwọn o si ronu rẹ pe, Eyi li ọkunrin na ti o mu aiye wárìrì, ti o mu ilẹ ọba mìtiti;

Isa 14

Isa 14:9-23