Isa 14:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NITORI Oluwa yio ṣãnu fun Jakobu, yio si tun yan Israeli, yio si mu wọn gbe ilẹ wọn; alejò yio si dapọ̀ mọ wọn, nwọn o si faramọ ile Jakobu.

Isa 14

Isa 14:1-2