Isa 13:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si dabi abo agbọ̀nrin ti a nlepa, ati bi agutan ti ẹnikan kò gbajọ: olukuluku wọn o yipada si enia rẹ̀, olukuluku yio si sa si ilẹ rẹ̀.

Isa 13

Isa 13:9-22