Isa 11:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

On o si gbe ọpagun kan duro fun awọn orilẹ-ède, yio si gbá awọn aṣati Israeli jọ, yio si kó awọn ti a tuka ni Juda jọ lati igun mẹrin aiye wá.

Isa 11

Isa 11:2-16