Isa 11:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati li ọjọ na kùkute Jesse kan yio wà, ti yio duro fun ọpágun awọn enia; on li awọn keferi yio wá ri: isimi rẹ̀ yio si li ogo.

Isa 11

Isa 11:3-16