Isa 10:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si jo ogo igbó rẹ̀ run, ati oko rẹ̀ ẹlẹtù loju, ati ọkàn ati ara: nwọn o si dabi igbati ọlọpagun ndakú.

Isa 10

Isa 10:13-25