Isa 1:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bikòṣe bi Oluwa awọn ọmọ-ogun ti fi iyokù diẹ kiun silẹ fun wa, awa iba ti dabi Sodomu, awa iba si ti dabi Gomorra.

Isa 1

Isa 1:4-14