Isa 1:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Alagbara yio si dabi ògùṣọ̀, iṣẹ rẹ̀ yio si dabi ẹta-iná, ati awọn mejeji yio jọ jona pọ̀, ẹnikẹni kì yio si pa wọn.

Isa 1

Isa 1:29-31