Isa 1:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina Oluwa, Oluwa awọn ọmọ-ogun, Ẹni alagbara Israeli, wipe, A, emi o fi aiya balẹ niti awọn ọtá mi, emi o si gbẹ̀san lara awọn ọtá mi.

Isa 1

Isa 1:15-27