Isa 1:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ilu otitọ ha ti ṣe di àgbere! o ti kún fun idajọ ri; ododo ti gbe inu rẹ̀ ri; ṣugbọn nisisiyi, awọn apania.

Isa 1

Isa 1:11-24