3. Joh 1:14-15 Yorùbá Bibeli (YCE)

14. Ṣugbọn mo ni ireti lati ri ọ laipẹ, a o si sọrọ li ojukoju.

15. Alafia fun ọ. Awọn ọrẹ́ kí ọ. Kí awọn ọrẹ́ li ọkọ̃kan.

3. Joh 1