2. Tim 3:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE) ṢUGBỌN eyi ni ki o mọ̀, pe ni ikẹhin ọjọ ìgbà ewu yio de. Nitori awọn enia yio jẹ olufẹ ti ara wọn