2. Tim 2:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina mo nfarada ohun gbogbo nitori ti awọn ayanfẹ, ki awọn na pẹlu le ni igbala ti mbẹ ninu Kristi Jesu pẹlu ogo ainipẹkun.

2. Tim 2

2. Tim 2:8-14