2. Tes 3:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃li awa kò si jẹ onjẹ ẹnikẹni lọfẹ; ṣugbọn ninu ãpọn ati lãlã li a nṣiṣẹ́ lọsan ati loru, ki awa ki o ma bã dẹruba ẹnikẹni ninu nyìn:

2. Tes 3

2. Tes 3:1-15