2. Tes 3:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori awa gburo awọn kan ti nrin ségesège larin nyìn ti nwọn kò nṣiṣẹ rara, ṣugbọn nwọn jẹ àtọjú-ile-kiri.

2. Tes 3

2. Tes 3:3-14