2. Sam 7:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Natani si wi fun ọba pe, Lọ, ki o si ṣe gbogbo eyi ti o wà li ọkàn rẹ, nitoripe Oluwa wà pẹlu rẹ.

2. Sam 7

2. Sam 7:2-12