2. Sam 5:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nigbati awọn Filistini gbọ́ pe, nwọn ti fi Dafidi jọba lori Israeli, gbogbo awọn Filistini si goke wá lati wa Dafidi; Dafidi si gbọ́, o si sọkalẹ lọ si ilu odi.

2. Sam 5

2. Sam 5:8-25