2. Sam 3:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Joabu ati gbogbo ogun ti o pẹlu rẹ̀ si de, nwọn si sọ fun Joabu pe, Abneri, ọmọ Neri ti tọ̀ ọba wá, on si ti rán a lọ, o si ti lọ li alafia.

2. Sam 3

2. Sam 3:21-26