2. Sam 3:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE) OGUN na si pẹ titi larin idile Saulu ati idile Dafidi: agbara Dafidi si npọ̀ si i, ṣugbọn idile Saulu nrẹ̀hin si