2. Sam 1:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Saulu ati Jonatani ni ifẹni si ara wọn, nwọn si dùn li ọjọ aiye wọn, ati ni ikú wọn, nwọn kò ya ara wọn: nwọn yara ju idì lọ, nwọn si li agbara ju kiniun lọ.

2. Sam 1

2. Sam 1:20-27