2. Sam 1:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ máṣe sọ ọ ni Gati, ẹ má si ṣe kokiki rẹ̀ ni igboro Aṣkeloni; ki awọn ọmọbinrin Filistini ki o má ba yọ̀, ki ọmọbinrin awọn alaikọla ki o má ba yọ̀.

2. Sam 1

2. Sam 1:10-25