2. Kro 9:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Àtẹgun mẹfa ni itẹ́ na ni, pẹlu apoti-itisẹ wura kan, ti a dè mọ itẹ́ na, ati irọpa ni iha mejeji ibi ijoko na, kiniun meji si duro lẹba awọn irọpa na.

2. Kro 9

2. Kro 9:9-28