2. Kro 8:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn enia ti o kù ninu awọn ara Hitti, ati awọn Amori, ati awọn Peresi, ati awọn Hifi ati awọn Jebusi, ti kì iṣe ti inu ọmọ Israeli.

2. Kro 8

2. Kro 8:1-8