2. Kro 5:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Solomoni pe awọn àgbagba Israeli jọ, ati gbogbo olori awọn baba awọn ọmọ Israeli si Jerusalemu, lati mu apoti-ẹri majẹmu Oluwa gòke lati ilu Dafidi wá, ti iṣe Sioni.

2. Kro 5

2. Kro 5:1-10