2. Kro 5:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Tobẹ̃ ti awọn alufa kò le duro lati ṣiṣẹ ìsin nitori awọsanmọ na: nitori ogo Oluwa kún ile Ọlọrun.

2. Kro 5

2. Kro 5:4-14