2. Kro 36:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati gbogbo ohun-elo ile Ọlọrun, nla ati kekere, ati iṣura ile Oluwa ati iṣura ọba, ati ti awọn ijoye rẹ̀; gbogbo wọn li o mu wá si Babeli.

2. Kro 36

2. Kro 36:12-23