2. Kro 34:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si mu ki gbogbo awọn ti o wà ni Jerusalemu ati Benjamini duro ninu rẹ̀, awọn ti ngbe Jerusalemu si ṣe gẹgẹ bi majẹmu Ọlọrun, Ọlọrun awọn baba wọn.

2. Kro 34

2. Kro 34:30-33